Àwọn Ọba Keji 15:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà Menahemu pa ìlú Tapua run, ati àwọn ìlú tí wọ́n yí i ká láti Tirisa, nítorí pé wọn kò ṣí ìlẹ̀kùn ìlú náà fún un, ó sì la inú gbogbo àwọn aboyún tí wọ́n wà níbẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:14-19