Àwọn Ọba Keji 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun tí ó dára lójú OLUWA, ṣugbọn kò dàbí ti Dafidi baba ńlá rẹ̀; ohun gbogbo tí Joaṣi baba rẹ̀ ṣe ni òun náà ṣe.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:1-6