Àwọn Ọba Keji 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè fún ọdún mọkandinlọgbọn ní Jerusalẹmu. Jehoadini, ará Jerusalẹmu, ni ìyá rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:1-11