Àwọn Ọba Keji 14:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kò pa àwọn pẹpẹ oriṣa run; àwọn eniyan ṣì ń rú ẹbọ níbẹ̀, wọ́n sì ń sun turari.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:1-10