Àwọn Ọba Keji 14:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Ní ọdún keji tí Jehoaṣi ọmọ Jehoahasi jọba ní Israẹli ni Amasaya ọmọ Joaṣi jọba ní Juda.