Àwọn Adájọ́ 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìjòyè Sukotu dá a lóhùn, wọ́n ní, “Ṣé ọwọ́ rẹ ti tẹ Seba ati Salimuna ni, tí a óo fi fún ìwọ ati àwọn ọmọ ogun rẹ ní oúnjẹ?”

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:2-10