Àwọn Adájọ́ 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bẹ àwọn ará Sukotu, ó ní, “Ẹ jọ̀wọ́, ẹ fún àwọn tí wọ́n tẹ̀lé mi ní oúnjẹ, nítorí pé ó ti rẹ̀ wọ́n, ati pé à ń lé Seba ati Salimuna, àwọn ọba Midiani mejeeji lọ ni.”

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:1-14