Àwọn Adájọ́ 8:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gideoni dá wọn lóhùn pé, “Kò burú, nígbà tí OLUWA bá fi Seba ati Salimuna lé mi lọ́wọ́, ẹ̀gún ọ̀gàn aṣálẹ̀ ati òṣùṣú ni n óo fi ya ẹran ara yín.”

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:6-12