Àwọn Adájọ́ 8:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò ranti OLUWA Ọlọrun wọn tí ó gbà wọ́n kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá wọn ní gbogbo àyíká wọn.

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:28-35