Àwọn Adájọ́ 8:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Gideoni ti ṣaláìsí tán gẹ́rẹ́, àwọn ọmọ Israẹli tún bẹ̀rẹ̀ sí bọ oriṣa Baali, wọ́n sì sọ Baali-beriti di Ọlọrun wọn.

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:29-35