Àwọn Adájọ́ 8:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Gideoni ọmọ Joaṣi ṣaláìsí lẹ́yìn tí ó ti di arúgbó, wọ́n sin ín sinu ibojì Joaṣi, baba rẹ̀, ní Ofira àwọn ọmọ Abieseri.

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:30-35