Àwọn Adájọ́ 8:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò ṣe ìdílé Gideoni dáradára bí ó ti tọ́, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀san gbogbo nǹkan dáradára tí òun náà ti ṣe fún Israẹli.

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:25-35