Àwọn Adájọ́ 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọba;ẹ tẹ́tí sílẹ̀ ẹ̀yin ìjòyè;OLUWA ni n óo kọrin sí,n óo kọrin dídùn sí OLUWA, Ọlọrun Israẹli.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:1-5