Àwọn Adájọ́ 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, nígbà tí o jáde lọ láti òkè Seiri,nígbà tí o jáde lọ láti agbègbè Edomu,ilẹ̀ mì tìtì,omi bẹ̀rẹ̀ sí bọ́,ọ̀wààrà òjò bẹ̀rẹ̀ sí rọ̀.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:1-12