Àwọn Adájọ́ 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fi ìyìn fún OLUWA,nítorí pé, àwọn olórí ni wọ́n ṣiwaju ní Israẹli,àwọn eniyan sì fi tọkàntọkàn fa ara wọn kalẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:1-6