Àwọn Adájọ́ 5:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Sebuluni fi ẹ̀mí wọn wéwu dójú ikú,bẹ́ẹ̀ náà sì ni àwọn ọmọ Nafutali,wọ́n fi ẹ̀mí ara wọn wéwu ninu pápá, lójú ogun.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:15-20