Àwọn Adájọ́ 5:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní Taanaki lẹ́bàá odò Megidoàwọn ọba wá, wọ́n jagun,wọ́n bá àwọn ọba Kenaani jagun,ṣugbọn wọn kò rí ìkógun fadaka kó.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:12-23