Àwọn Adájọ́ 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Gileadi dúró ní ìlà oòrùn odò Jọdani,kí ló dé tí ẹ̀yà Dani fi dúró ní ìdí ọkọ̀ ojú omi?Àwọn ẹ̀yà Aṣeri jókòó létí òkun,wọ́n wà ní ẹsẹ̀ odò.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:12-21