Àwọn Adájọ́ 5:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ló dé tí o fi dúró lẹ́yìn láàrin àwọn agbo aguntan?Tí o fi ń gbọ́ bí àwọn olùṣọ́-aguntan ti ń fọn fèrè fún àwọn aguntan wọn.Àwọn ẹ̀yà Reubẹni ṣiyèméjì,ìmọ̀ wọn kò ṣọ̀kan láti wá.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:14-22