Àwọn Adájọ́ 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìjòyè Isakari náà bá Debora wá,àwọn ọmọ Isakari jẹ́ olóòótọ́ sí Baraki,wọ́n sì dà tẹ̀lé e lẹ́yìn lọ sí àfonífojì.Àwọn ẹ̀yà Reubẹni ṣiyèméjì,ìmọ̀ wọn kò ṣọ̀kan láti wá.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:14-25