Àwọn Adájọ́ 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwọn ọmọ Israẹli ń gbé ààrin àwọn ará Kenaani ati àwọn ará Hiti, àwọn ará Amori ati àwọn ará Perisi, àwọn ará Hifi, ati àwọn ará Jebusi.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:2-10