Àwọn Adájọ́ 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ni OLUWA fi dán àwọn ọmọ Israẹli wò, láti wò ó bóyá wọn óo mú àṣẹ tí òun pa fún àwọn baba wọn láti ọwọ́ Mose ṣẹ, tabi wọn kò ní mú un ṣẹ.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:1-9