Àwọn Adájọ́ 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ń fẹ́mọ lọ́wọ́ àwọn eniyan orílẹ̀-èdè náà, àwọn náà ń fi ọmọ fún wọn; àwọn ọmọ Israẹli sì ń bọ àwọn oriṣa wọn.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:2-10