Àwọn Adájọ́ 3:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ Israẹli ṣe ṣẹgun wọn ní ọjọ́ náà, ilẹ̀ náà sì wà ní alaafia fún ọgọrin ọdún.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:28-31