Àwọn Adájọ́ 3:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n pa àwọn alágbára ati akikanju bí ẹgbaarun (10,000) ninu àwọn ará Moabu, kò sì sí ẹnìkan tí ó là ninu wọn.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:22-31