Àwọn Adájọ́ 3:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Aṣiwaju tí ó tún dìde lẹ́yìn Ehudu ni Ṣamgari, ọmọ Anati, ẹni tí ó fi ọ̀pá tí wọ́n fi ń da mààlúù pa ẹgbẹta (600) ninu àwọn ará Filistia; òun náà gba Israẹli kalẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:24-31