Àwọn Adájọ́ 3:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo ìgbà tí àwọn iranṣẹ wọnyi ń dúró pé kí ọba ṣílẹ̀kùn, Ehudu ti sá lọ, ó sì ti kọjá òkúta gbígbẹ́ tí ó wà lẹ́bàá Giligali, ó ti sá dé Seira.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:18-31