Àwọn Adájọ́ 3:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dúró títí tí agara fi dá wọn. Ṣugbọn nígbà tí ó kọ̀ tí kò ṣí ìlẹ̀kùn, wọ́n bá mú kọ́kọ́rọ́, wọ́n ṣí àwọn ìlẹ̀kùn; wọ́n bá bá òkú oluwa wọn nílẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:24-31