Àwọn Adájọ́ 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA fi àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi sílẹ̀ láti fi dán Israẹli wò, pàápàá jùlọ, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí wọn kò tíì ní ìrírí ogun jíjà ní ilẹ̀ Kenaani.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:1-8