Àwọn Adájọ́ 2:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA fi àwọn orílẹ̀-èdè náà sílẹ̀ ninu ilẹ̀ náà, kò tètè lé wọn jáde bí kò ti fún Joṣua lágbára láti ṣẹgun wọn.

Àwọn Adájọ́ 2

Àwọn Adájọ́ 2:16-23