Àwọn Adájọ́ 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ni n óo lò láti wò ó bí àwọn ọmọ Israẹli yóo máa tọ ọ̀nà tí mo là sílẹ̀, bí àwọn baba ńlá wọn ti ṣe.”

Àwọn Adájọ́ 2

Àwọn Adájọ́ 2:12-23