Àwọn Adájọ́ 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn ọmọ Israẹli lè mọ̀ nípa ogun jíjà, pataki jùlọ, ìṣọ̀wọ́ àwọn tí wọn kò mọ̀ nípa ogun jíjà tẹ́lẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:1-7