Àwọn Adájọ́ 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ti búra nígbà tí wọ́n wà ní Misipa pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wa kò ní fi ọmọ rẹ̀ fún ará Bẹnjamini.”

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:1-11