Àwọn Adájọ́ 21:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan bá wá sí Bẹtẹli, wọ́n jókòó níwájú Ọlọrun títí di ìrọ̀lẹ́, wọ́n sì sọkún gidigidi.

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:1-11