Àwọn Adájọ́ 20:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli bá yipada sí àwọn ará Bẹnjamini, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí pa gbogbo àwọn tí wọ́n bá fojú kàn, ati eniyan ati ẹranko. Gbogbo ìlú wọn tí wọ́n rí ni wọ́n sì sun níná.

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:38-48