Àwọn Adájọ́ 20:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ Lefi, ọkọ obinrin tí wọ́n pa, bá dáhùn pé, “Èmi ati obinrin mi ni a yà sí Gibea ní ilẹ̀ àwọn ará Bẹnjamini pé kí á sùn níbẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:1-6