Àwọn Adájọ́ 20:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin Gibea bá dìde lóru, wọ́n yí ilé tí mo wà po, wọ́n fẹ́ pa mí. Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bá obinrin mi lòpọ̀ títí tí ó fi kú.

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:1-6