Àwọn Adájọ́ 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹ̀yà Bẹnjamini gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli ti kó ara wọn jọ ní Misipa.Àwọn ọmọ Israẹli bèèrè lọ́wọ́ ọmọ Lefi náà pé, “Sọ fún wa, báwo ni nǹkan burúkú yìí ti ṣe ṣẹlẹ̀?”

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:1-5