Àwọn Adájọ́ 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa náà dá wọn lóhùn pé, “Ẹ máa lọ ní alaafia, Ọlọrun fọwọ́ sí ìrìn àjò tí ẹ̀ ń lọ.”

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:5-10