Àwọn Adájọ́ 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá bẹ̀ ẹ́ pé, “Jọ̀wọ́, bá wa wádìí lọ́dọ̀ Ọlọrun, kí á lè mọ̀ bóyá ìrìn àjò tí à ń lọ yìí yóo yọrí sí rere.”

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:1-12