Àwọn Adájọ́ 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí wọ́n ti rìn jìnnà sí ilé Mika, Mika pe gbogbo àwọn aládùúgbò rẹ̀ jọ, wọ́n sì lé àwọn ará Dani bá.

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:21-30