Àwọn Adájọ́ 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kígbe pè wọ́n, àwọn ará Dani bá yipada, wọn bi Mika pé, “Kí ní ń dà ọ́ láàmú tí o fi ń bọ̀ pẹlu ọpọlọpọ eniyan báyìí?”

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:13-28