Àwọn Adájọ́ 18:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kúrò níbẹ̀, wọ́n ń lọ. Àwọn ọmọ wẹ́wẹ́, àwọn ẹran ọ̀sìn wọn ati àwọn ẹrù wọn ń lọ níwájú wọn.

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:18-25