Àwọn Adájọ́ 18:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú alufaa náà bá dùn, ó gbé ẹ̀wù efodu, ó kó àwọn ère kékeré náà ati ère dídà náà, ó ń bá àwọn eniyan náà lọ.

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:19-27