Àwọn Adájọ́ 13:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin náà bá sáré lọ sọ fún ọkọ rẹ̀, ó ní, “Ẹni tí ó wá sọ́dọ̀ mi níjọ́sí tún ti fara hàn mí.”

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:6-17