Àwọn Adájọ́ 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Manoa bá gbéra, ó bá tẹ̀lé iyawo rẹ̀ lọ sọ́dọ̀ ọkunrin náà, ó bi í pé, “Ṣé ìwọ ni o bá obinrin yìí sọ̀rọ̀?”Ọkunrin náà dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni.”

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:5-12