Àwọn Adájọ́ 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun gbọ́ adura Manoa, angẹli Ọlọrun náà tún pada tọ obinrin yìí wá níbi tí ó jókòó sí ninu oko; ṣugbọn Manoa, ọkọ rẹ̀, kò sí lọ́dọ̀ rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:6-19