Àwọn Adájọ́ 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ohun tí Kemoṣi, oriṣa rẹ fún ọ, kò tó ọ ni? Gbogbo ohun tí OLUWA Ọlọrun wa ti gbà fún wa ni a óo fọwọ́ mú.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:20-27