Àwọn Adájọ́ 11:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun Israẹli ni ó gba ilẹ̀ náà lọ́wọ́ àwọn ará Amori fún àwọn ọmọ Israẹli. Ṣé ìwọ wá fẹ́ gbà á ni?

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:17-29