Àwọn Adájọ́ 11:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ìwọ sàn ju Balaki, ọmọ Sipori, ọba Moabu lọ ni? Ǹjẹ́ Balaki bá àwọn ọmọ Israẹli ṣe ìjàngbọ̀n kan tabi kí ó bá wọn jagun rí?

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:24-30